@ O Dabi Eni Wipe Eyin Alaroye Nilo Ayipada Oruko Yin Si Alawiye, Toripe Isokuso Loku Ti E U'nso... Se Awon Hausa Wa Le Da Oko To Iran Yoruba Ni? Abi Se Ile North Lora To Ile South Ni? Ki Won Tete Ma Ta Ere Oko Won Si Orun Pelu, Ko Kan Wa.... Aalafia Ti Yoruba Unfe Gba Laye Lo Fe Se Akoba Fun Fun Wa... Ani Ki Nigeria Pin, Ki Kaluku Mo Iwon Arare...
Kosi iyan kankan kiwon tete ma ta si ilu oyinbo.... Awa karo ojire bii.. Ile Yoruba awa na ni ile janturu lati fi da oko oun ogbin .. Ki awon jagunjagun ile Yoruba bawa le awon Fulani kidnapper danu ni inu oko wa... Yoruba tini ona abayo si ounje ni ile Yoruba.... Ebi kole pa ile Yoruba lailai..
Good idea, this will make Southerners serious about agriculture, especially we Yorubas.
Oro won ye wa.
Won fe bere ohun ti won ko ni le pari
They never confess what is paining them 😂😂
Ki Tinubu sii bordda Cotonou fun one rira
Iyan kini nbo? Se eyin ko mo ona oko ni?
@@stephenbabalola3613 Abi oo
Odara be, ani ile olora ni southernal, se bi otun masofo mowon lowo, kan ma lowa mo, enu won magbe.
Kiwan bawa si boda o
Ori won buru olorun yoje ki won ta awon eni bibi gbogbo gbo won o ni gbadun awon were gbogbo
@ O Dabi Eni Wipe Eyin Alaroye Nilo Ayipada Oruko Yin Si Alawiye, Toripe Isokuso Loku Ti E U'nso... Se Awon Hausa Wa Le Da Oko To Iran Yoruba Ni? Abi Se Ile North Lora To Ile South Ni? Ki Won Tete Ma Ta Ere Oko Won Si Orun Pelu, Ko Kan Wa.... Aalafia Ti Yoruba Unfe Gba Laye Lo Fe Se Akoba Fun Fun Wa... Ani Ki Nigeria Pin, Ki Kaluku Mo Iwon Arare...
We will start importing garri by December or next January because farmers can not enter farms anymore.
Better, it's because of tax refunds bill
Ile ti fe gbinsi
E jeki ari
Oro buruku. Eyi fihan wipe Yoruba kole da Duro. Wahala, wahala nikan ni to Yoruba. O ma se o?
Kosi iyan kankan kiwon tete ma ta si ilu oyinbo.... Awa karo ojire bii.. Ile Yoruba awa na ni ile janturu lati fi da oko oun ogbin .. Ki awon jagunjagun ile Yoruba bawa le awon Fulani kidnapper danu ni inu oko wa... Yoruba tini ona abayo si ounje ni ile Yoruba.... Ebi kole pa ile Yoruba lailai..
Tinubu should open border then.